
MUSIC
Ọlọ́run Gbé Ọwọ́ Lé Mi
From Gbé Ọwọ́ Lé Mi · Rev. Dunamis
Listen to album on Spotify↗Listen on Apple Music↗Listen on YouTube Music↗Listen on Deezer↗Listen on Boomplay↗Listen on Audiomack↗Listen on Tidal↗DISTROKID RELEASE VIDEO
Lyrics
Ọlọ́run ìgbà ni
Ọlọ́run ìgbà ni
Jésù Kristi
Ọ̀kan náà ni lánàá, àti lónìí, àti títí láé
Ọlọ́run Babalọlá
Ọlọ́run Òkè Ìgbà ni
Ọlọ́run nineteen thirty
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Ọlọ́run Idahosa
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Ọlọ́run Uma Ukpai
Níbi gbogbo ló wà
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Ọlọ́run Adeboye
Somebody Shout Halleluyah!
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Ọlọ́run Oyedepo
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Jésù Kristi
Ọ̀kan náà ni títí láé
Ọlọ́run Wale Oke
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Ọlọ́run Kumuyi
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun Baba Abiara
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Ọlọ́run Olukoya
Power must change hands
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun Oyakhilome
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun Ashimolowo
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun Adelakun
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun Ajetomobi
Missions to the core
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun George Adegboye
Bible Encyclopaedia
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun Adejumo
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun Tunde Joda
Awon ti Word of Faith
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun Victor Adeyemi
Healing Anointing
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun Sam Adeyemi
Success Power
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun Poju Oyemade
Baba WOFBEC
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun David Ogbueli
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun Ibieyomie
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Olorun Enenche
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Ọlọ́run àwọn baba wa
Ọlọ́run àwọn iran wa
Ọlọ́run tó ń ṣe iṣẹ́ Rẹ̀
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Lánàá, Jésù ni
Lónìí, Jésù ni
Títí láé, Jésù ni
Ọ̀kan náà ni Jésù
Àwọn ènìyàn ń kọjá
Ṣùgbọ́n Ọ̀rọ̀ Rẹ̀ dúró
Àwọn iran ń yí padà
Ṣùgbọ́n Jésù kì í yí padà
Ta ni Ọlọ́run wa?
Jésù Kristi
Ta ni ń gbé ọwọ́ lé wa?
Jésù Kristi
Ta ni ọ̀kan náà lánàá?
Jésù Kristi
Ta ni ọ̀kan náà títí láé?
Jésù Kristi
Ọlọ́run Babalọlá
Ọlọ́run Idahosa
Ọlọ́run Adeboye
Ọlọ́run Oyedepo
Ọlọ́run Wale Oke
Ọlọ́run Kumuyi
Olorun Baba Abiara
Ọlọ́run Olukoya
Olorun Oyakhilome
Olorun Ashimolowo
Olorun Adelakun
Olorun Ajetomobi
lOorun George Adegboye
Olorun Adejumo
Olorun Tunde Joda
Olorun Victor Adeyemi
Olorun Sam Adeyemi
Olorun Poju Oyemade
Olorun David Ogbueli
Olorun Ibieyomie
Olorun Enenche
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi
Jésù Kristi
Ọ̀kan náà ni lánàá
Ọ̀kan náà ni lónìí
Ọ̀kan náà ni títí láé
Ọlọ́run gbé ọwọ́ lé mi